Gẹn 47:30 YCE

30 Ṣugbọn nigbati emi ba sùn pẹlu awọn baba mi, iwọ o gbe mi jade ni Egipti, ki o si sin mi ni iboji wọn. On si wipe, Emi o ṣe bi iwọ ti wi.

Ka pipe ipin Gẹn 47

Wo Gẹn 47:30 ni o tọ