Gẹn 48:9 YCE

9 Josefu wi fun baba rẹ̀ pe, Awọn ọmọ mi ni, ti Ọlọrun fifun mi nihinyi. O si wipe, Emi bẹ̀ ọ, mú wọn wá sọdọ mi, emi o si sure fun wọn.

Ka pipe ipin Gẹn 48

Wo Gẹn 48:9 ni o tọ