Gẹn 8:19 YCE

19 Gbogbo ẹranko, gbogbo ohun ti nrakò, ati ẹiyẹ gbogbo, ati ohunkohun ti nrakò lori ilẹ, gẹgẹ bi irú ti wọn, nwọn jade ninu ọkọ̀.

Ka pipe ipin Gẹn 8

Wo Gẹn 8:19 ni o tọ