4 Rámù ni baba Ámínádábù;Ámínádábù ni baba Náhísónì;Náhísónì ni baba Sálímónì;
5 Sálímónì ni baba Bóásì, Ráhábù sí ni ìyá rẹ̀;Bóásì ni baba Óbédì, Rúùtù sí ni ìyá rẹ̀;Óbédì sì ni baba Jésè;
6 Jésè ni baba Dáfídì ọba.Dáfídì ni baba Sólómónì, ẹni tí ìyá rẹ̀ jẹ́ aya Húráyà tẹ́lẹ̀ rí.
7 Sólómónì ni baba Réhóbóámù,Réhóbóámù ni baba Ábíjà,Ábíjà ni baba Ásà,
8 Áṣà ni baba Jéhósáfátì;Jéhósafátì ni baba Jéhórámù;Jéhórámù ni baba Húsáyà;
9 Húsáyà ni baba Jótámù;Jótámù ni baba Áhásì;Áhásì ni baba Heṣekáyà;
10 Heṣekáyà ni baba Mánásè;Mánásè ni baba Ámónì;Ámónì ni baba Jósáyà;