8 Áṣà ni baba Jéhósáfátì;Jéhósafátì ni baba Jéhórámù;Jéhórámù ni baba Húsáyà;
9 Húsáyà ni baba Jótámù;Jótámù ni baba Áhásì;Áhásì ni baba Heṣekáyà;
10 Heṣekáyà ni baba Mánásè;Mánásè ni baba Ámónì;Ámónì ni baba Jósáyà;
11 Jósáyà sì ni baba Jékónáyà àti àwọn arákùnrin rẹ̀ ní àkókò ìkólọ sí Bábílónì.
12 Lẹ́yìn ìkólọ sí Bábílónì:Jékónáyà ni baba Selítílì;Selítílì ni baba Sérúbábélì;
13 Sèrérúbábélì ni baba Ábíúdì;Ábíúdì ni baba Élíákímù;Élíákímù ni baba Ásórì;
14 Ásórì ni baba Sádókù;Sádókù ni baba Ákímù;Ákímù ni baba Élíúdì;