Mátíù 11:4 BMY

4 Jésù dáhùn ó wí pé, “Ẹ padà lọ, ẹ sì sọ fún Jòhánù ohun tí ẹ̀yin gbọ́, àti èyí tí ẹ̀yin rí.

Ka pipe ipin Mátíù 11

Wo Mátíù 11:4 ni o tọ