Mátíù 12:2 BMY

2 Nígbà tí àwọn Farisí rí èyí. Wọ́n wí fún pé, “Wò ó! Àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ ń ṣe ohun tí kò bá òfin mu ní ọjọ́ ìsinmi.”

Ka pipe ipin Mátíù 12

Wo Mátíù 12:2 ni o tọ