Mátíù 12:33 BMY

33 “E ṣọ igi di rere, èso rẹ̀ a sì di rere tàbí kí ẹ sọ igi di búburú, èso rẹ a sì di búburú, nítorí nípa èso igi ni a ó fi mọ̀ ọ́n.

Ka pipe ipin Mátíù 12

Wo Mátíù 12:33 ni o tọ