Mátíù 12:38 BMY

38 Nígbà náà ni, díẹ̀ nínú àwọn Farisí àti àwọn olùkọ́ òfin wí fún pé “Olùkọ́, àwa fẹ́ rí iṣẹ́ àmì kan lọ́dọ̀ rẹ̀”.

Ka pipe ipin Mátíù 12

Wo Mátíù 12:38 ni o tọ