Mátíù 12:4 BMY

4 Ó wọ inú ilé Ọlọ́run, òun àti àwọn ènìyàn rẹ̀ jẹ àkàrà tí a yà sọ́tọ̀, èyí tí kò yẹ fún wọn láti jẹ, bí kò se fún àwọn àlùfáà nìkan.

Ka pipe ipin Mátíù 12

Wo Mátíù 12:4 ni o tọ