Mátíù 13:2 BMY

2 Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn péjọ sọ́dọ̀ rẹ̀, tó bẹ́ẹ̀ tí ó fi bọ́ sínú ọkọ̀-ojú omi, ó jókòó, gbogbo ènìyàn sì dúró létí òkun.

Ka pipe ipin Mátíù 13

Wo Mátíù 13:2 ni o tọ