Mátíù 13:31 BMY

31 Jésù tún pa òwe mìíràn fún wọn: “Ìjọba ọ̀run dàbí èso hóró músítádì, èyí tí ọkùnrin kan mú tí ó gbìn sínú oko rẹ̀.

Ka pipe ipin Mátíù 13

Wo Mátíù 13:31 ni o tọ