Mátíù 13:39 BMY

39 ọ̀tá tí ó gbin àwọn èpò sáàrin àlìkámà ni èṣù. Ìkórè ni òpin ayé, àwọn olùkórè sì ní àwọn ańgẹ́lì.

Ka pipe ipin Mátíù 13

Wo Mátíù 13:39 ni o tọ