Mátíù 14:12 BMY

12 Lẹ́yìn náà, àwọn ọmọ-ẹ̀yìn Jòhánù wá gba òkú rẹ̀, wọ́n sì sin ín. Wọ́n sì wá sọ ohun tí ó ṣẹlẹ̀ fún Jésù.

Ka pipe ipin Mátíù 14

Wo Mátíù 14:12 ni o tọ