Mátíù 14:14 BMY

14 Nígbà ti Jésù gúnlẹ̀, tí ó sì rí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn, inú rẹ̀ yọ́ sí wọn, ò sì mú àwọn aláìsàn láradá.

Ka pipe ipin Mátíù 14

Wo Mátíù 14:14 ni o tọ