Mátíù 14:24 BMY

24 ní àkókò yìí ọkọ ojú-omi náà ti rin jìnnà sí etí bèbè òkun, tí ìjì omi ń tì í síwá sẹ́yìn, nítorí ìjì ṣe ọwọ́ òdì sí wọn.

Ka pipe ipin Mátíù 14

Wo Mátíù 14:24 ni o tọ