Mátíù 14:35 BMY

35 Nígbà ti wọn mọ̀ pé Jésù ni, wọn sì ránṣẹ́ sí gbogbo ìlú náà yíká. Wọ́n sì gbé gbogbo àwọn aláìsàn tọ̀ ọ́ wá.

Ka pipe ipin Mátíù 14

Wo Mátíù 14:35 ni o tọ