Mátíù 15:18 BMY

18 Ṣùgbọ́n ohun tí a ń sọ jáde láti ẹnu, inú ọkàn ni ó ti ń wá, èyí sì ni ó ń sọ ènìyàn di ‘aláìmọ́.’

Ka pipe ipin Mátíù 15

Wo Mátíù 15:18 ni o tọ