Mátíù 15:20 BMY

20 Àwọn tí a dárúkọ wọ̀nyí ni ó ń sọ ènìyàn di ‘aláìmọ́.’ Ṣùgbọ́n láti jẹun láì wẹ ọwọ́, kò lè sọ ènìyàn di ‘aláìmọ́.’ ”

Ka pipe ipin Mátíù 15

Wo Mátíù 15:20 ni o tọ