Mátíù 15:27 BMY

27 Obìnrin náà sì wí pé, “Bẹ́ẹ̀ ni, síbẹ̀síbẹ̀ àwọn ajá a máa jẹ èérún tí ó ti orí tábìlì olówó wọn bọ́ sílẹ̀.”

Ka pipe ipin Mátíù 15

Wo Mátíù 15:27 ni o tọ