Mátíù 16:1 BMY

1 Àwọn Farisí àti àwọn Sadusí wá láti dán Jésù wò. Wọ́n ní kí ó fi àmì ńlá kan hàn àwọn ní ojú ọ̀run.

Ka pipe ipin Mátíù 16

Wo Mátíù 16:1 ni o tọ