Mátíù 17:1 BMY

1 Lẹ́yìn ọjọ́ mẹ́fà, Jésù mú Pétérù, Jákọ́bù àti Jòhánù arákùnrin rẹ̀ Jákọ́bù, ó mú wọn lọ sí orí òkè gíga kan tí ó dá dúró.

Ka pipe ipin Mátíù 17

Wo Mátíù 17:1 ni o tọ