Mátíù 17:15 BMY

15 “Olúwa, ṣàánú fún ọmọ mi, nítorí tí ó ní wárápá. Ó sì ń joró gidigidi, nígbà púpọ̀ ni ó máa ń ṣubu sínú iná tàbí sínú omi.

Ka pipe ipin Mátíù 17

Wo Mátíù 17:15 ni o tọ