Mátíù 17:17 BMY

17 Jésù sì dáhùn wí pé, “A! ẹ̀yìn alágídí ọkàn àti aláìgbàgbọ́ ènìyàn, èmi yóò ti bá yín gbé pẹ́ tó? Èmi ó sì ti fara dà á fún yín tó? Ẹ mú un wá sọ́dọ̀ mi níhìn-ín yìí.”

Ka pipe ipin Mátíù 17

Wo Mátíù 17:17 ni o tọ