Mátíù 17:22 BMY

22 Nígbà tí wọ́n sì ti wà ní Gálílì, Jésù sọ fún wọn pé, “Láìpẹ́ yìí a ó fi Ọmọ ènìyàn lé àwọn ènìyàn lọ́wọ́.

Ka pipe ipin Mátíù 17

Wo Mátíù 17:22 ni o tọ