Mátíù 17:27 BMY

27 ‘Ṣíbẹ̀ṣíbẹ̀, àwa kò fẹ́ mú wọn bínú’ Nítorí náà, ẹ lọ sí etí òkun, kí ẹ sì sọ ìwọ̀ sí omi. Ẹ mú ẹja àkọ́kọ́ tí ẹ kọ́ fà sókè, ẹ ya ẹnu rẹ̀, ẹ̀yin yóò sì rí owó idẹ kan níbẹ̀, ki ẹ fi fún wọn fún owó-orí tèmi àti tirẹ̀.”

Ka pipe ipin Mátíù 17

Wo Mátíù 17:27 ni o tọ