Mátíù 19:10 BMY

10 Àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ wí fún un pé, “Bí ọ̀rọ̀ bá rí báyìí láàrin ọkọ àti aya, kó ṣààfààní fún wa láti gbé ìyàwó.”

Ka pipe ipin Mátíù 19

Wo Mátíù 19:10 ni o tọ