Mátíù 19:14 BMY

14 Ṣùgbọ́n Jésù dáhùn pé, “Ẹ jẹ́ kí àwọn ọmọdé wá sọ́dọ̀ mi, ẹ má ṣe dá wọn lẹ́kun, nítorí irú wọn ni ìjọba ọ̀run.”

Ka pipe ipin Mátíù 19

Wo Mátíù 19:14 ni o tọ