Mátíù 19:20 BMY

20 Ọmọdékùnrin náà tún wí pé, “Gbogbo òfin wọ̀nyí ni èmi ti ń pamọ́, kí ni nǹkan mìíràn tí èmi mo ní láti ṣe?”

Ka pipe ipin Mátíù 19

Wo Mátíù 19:20 ni o tọ