Mátíù 19:22 BMY

22 Ṣùgbọ́n nígbà tí ọ̀dọ́mọkùnrin náà gbọ́ èyí, ó kúrò níbẹ̀ pẹ̀lú ìbànújẹ́, nítorí ó ní ọrọ̀ púpọ̀.

Ka pipe ipin Mátíù 19

Wo Mátíù 19:22 ni o tọ