Mátíù 19:8 BMY

8 Jésù dáhùn pé, “Mósè yọ̀ǹda kí ẹ kọ aya yín sílẹ̀ nítorí ọkàn yín le. Ṣùgbọ́n kò rí bẹ́ẹ̀ láti àtètèkọ́ṣe.

Ka pipe ipin Mátíù 19

Wo Mátíù 19:8 ni o tọ