Mátíù 2:12 BMY

12 Nítorí pé Ọlọ́run ti kìlọ̀ fún wọn ní ojú àlá pé kí wọ́n má ṣe padà tọ Hérọ́dù lọ mọ́, wọ́n gba ọ̀nà mìíràn lọ sí ìlú wọn.

Ka pipe ipin Mátíù 2

Wo Mátíù 2:12 ni o tọ