Mátíù 2:23 BMY

23 ó sì lọ í gbé ní ìlú tí a pè ní Násárẹ́tì. Nígbà náà ni èyí tí a sọ tẹ́lẹ̀ láti ẹnu àwọn wòlíì wá sí ìmúṣẹ: “A ó pè é ní ará Násárẹ́tì.”

Ka pipe ipin Mátíù 2

Wo Mátíù 2:23 ni o tọ