Mátíù 2:3 BMY

3 Nígbà tí ọba Hẹ́rọ́dù sì gbọ́ èyí, ìdáàmú bá a àti gbogbo àwọn ara Jerúsálémù pẹ̀lú rẹ̀

Ka pipe ipin Mátíù 2

Wo Mátíù 2:3 ni o tọ