Mátíù 20:1 BMY

1 “Nítorí ìjọba ọ̀run dàbí ọkùnrin tí ó jẹ́ baálé kan, tí ó jí jáde lọ ní kùtùkùtù òwúrọ̀, tí ó gba àwọn alágbàṣe sínú ọgbà àjàrà rẹ̀.

Ka pipe ipin Mátíù 20

Wo Mátíù 20:1 ni o tọ