Mátíù 20:29 BMY

29 Bí Jésù àti àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ ti ń fi ìlú Jẹ́ríkò sílẹ̀, ọ̀pọ̀ ènìyàn sì wọ́ tẹ̀lé e lẹ́yìn.

Ka pipe ipin Mátíù 20

Wo Mátíù 20:29 ni o tọ