Mátíù 20:31 BMY

31 Àwọn ènìyàn sí bá wọn wí pé kí wọn dákẹ́, ṣùgbọ́n wọ́n kígbe sóke sí i. “Olúwa, ọmọ Dáfídì, ṣàánú fún wa!”

Ka pipe ipin Mátíù 20

Wo Mátíù 20:31 ni o tọ