Mátíù 20:34 BMY

34 Àánú wọn sì ṣe Jésù, ó fi ọwọ́ kan ojú wọn. Lójú kan náà, wọ́n sì ríran, wọ́n sì ń tọ̀ ọ́ lẹ́yìn.

Ka pipe ipin Mátíù 20

Wo Mátíù 20:34 ni o tọ