Mátíù 21:10 BMY

10 Bí Jésù sì ti ń wọ Jerúsálémù, gbogbo ìlú mì tìtì, àwọn ènìyàn bẹ̀rẹ̀ sí í bi ara wọn pé, “Ta nì yìí?”

Ka pipe ipin Mátíù 21

Wo Mátíù 21:10 ni o tọ