Mátíù 22:12 BMY

12 Ọba sì bi í pé, ‘Ọ̀rẹ́, báwo ni ìwọ ṣe wà níhìn-ín yìí láì ní aṣọ ìgbéyàwó?’ Ṣùgbọ́n ọkùnrin náà kò ní ìdáhùn kankan.

Ka pipe ipin Mátíù 22

Wo Mátíù 22:12 ni o tọ