Mátíù 22:15 BMY

15 Nígbà náà ni àwọn Farisí pé jọ pọ̀ láti ronú ọ̀nà tì wọn yóò gbà fi ọ̀rọ̀ ẹnu mú un.

Ka pipe ipin Mátíù 22

Wo Mátíù 22:15 ni o tọ