Mátíù 23:14 BMY

14 “Ègbé ni fún yín, ẹ̀yin olùkọ́ òfin àti Farisí, ẹ̀yin àgàbàgebè! nítorí ẹ̀yin jẹ ilé àwọn opó run, àti nítorí àṣehàn, ẹ̀ ń gbàdúrà gígùn, nítorí náà ni ẹ̀yin yóò ṣe jẹ̀bí púpọ̀.

Ka pipe ipin Mátíù 23

Wo Mátíù 23:14 ni o tọ