Mátíù 23:18 BMY

18 Àti pé, Ẹmikẹ́ni tó bá fi pẹpẹ búra, kò já mọ́ nǹkan, ṣùgbọ́n bí ẹnikẹ́ni tí ó ba fi ẹ̀bùn tí ó wà lórí rẹ̀ búra, ó di ajigbèsè.

Ka pipe ipin Mátíù 23

Wo Mátíù 23:18 ni o tọ