Mátíù 23:4 BMY

4 Wọ́n á di ẹrù wúwo tí ó sì ṣòro láti rù, wọ́n a sì gbé e le àwọn ènìyàn léjìká, ṣùgbọ́n àwọn tìkára wọn kò jẹ́ fi ìka wọn kan an.

Ka pipe ipin Mátíù 23

Wo Mátíù 23:4 ni o tọ