Mátíù 24:14 BMY

14 A ó sì wàásù ìyìn rere nípa ìjọba náà yí gbogbo ayé ká, kí gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè lè gbọ́ ọ, nígbà náà ni òpin yóò dé ní ìkẹyìn.

Ka pipe ipin Mátíù 24

Wo Mátíù 24:14 ni o tọ