Mátíù 24:21 BMY

21 Nítorí ìpọ́njú ńlá yóò wà, irú èyí tí kò tí ì sẹlẹ̀ láti ìgbà ìbẹ̀rẹ̀ ọjọ́ ayé wá títí di ìsinsìn yìí irú rẹ̀ kì yóò sì sí.

Ka pipe ipin Mátíù 24

Wo Mátíù 24:21 ni o tọ