Mátíù 24:23 BMY

23 Nígbà náà, bí ẹnikẹ́ni bá sọ fún yín pé, ‘Wo Kírísítì náà,’ tàbí pé ó ti farahàn níhìn-ín tàbí lọ́hùn-ún, ẹ má ṣe gbà á gbọ́.

Ka pipe ipin Mátíù 24

Wo Mátíù 24:23 ni o tọ