Mátíù 24:27 BMY

27 Nítorí bí mọ̀nàmọ́ná ti ń tàn láti ìlà-òòrùn títí dé ìwọ̀-oòrun, bẹ́ẹ̀ ni wíwá Ọmọ-Ènìyàn yóò jẹ́.

Ka pipe ipin Mátíù 24

Wo Mátíù 24:27 ni o tọ