Mátíù 24:5 BMY

5 Nítorí ọ̀pọ̀ yóò wá ní orúkọ mi tí wọn yóò máa pe ara wọn ní Kírísítì náà. Wọn yóò ṣi ọ̀pọ̀lọpọ̀ lọ́nà.

Ka pipe ipin Mátíù 24

Wo Mátíù 24:5 ni o tọ