Mátíù 24:9 BMY

9 “Nígbà náà ni a ó sì dá a yín lóró. A ó pa yín, a ó sì kórìíra yín ni gbogbo ayé, nítorí pé ẹ̀yin jẹ́ tèmi.

Ka pipe ipin Mátíù 24

Wo Mátíù 24:9 ni o tọ